Knowledge Base Wiki

Search for LIMS content across all our Wiki Knowledge Bases.

Type a search term to find related articles by LIMS subject matter experts gathered from the most trusted and dynamic collaboration tools in the laboratory informatics industry.

Mercedes McCambridge
Mercedes McCambridge
Ọjọ́ìbíCarlotta Mercedes Agnes McCambridge
(1916-03-16)Oṣù Kẹta 16, 1916
Joliet, Illinois
AláìsíMarch 2, 2004(2004-03-02) (ọmọ ọdún 87)
La Jolla, California
Iléẹ̀kọ́ gígaMundelein College
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1930s–2004
Olólùfẹ́
  • William Fifield
    (m. 1939; div. 1946)
  • Fletcher Markle
    (m. 1950; div. 1962)
Àwọn ọmọ1

Mercedes McCambridge ni à bini ọjọ kẹfadinlógun óṣu March, ọdun 1916 ti ó si ku ni ọdun 2004 jẹ óṣèrè lóbinrin ti Radio, Stage, Film ati Television ilẹ America to gba Ebun Akademi bi Obinrin osere keji to dara ju lo. [1][2]

Igbèsi Àyè Àràbírin naa

McCambridge ni a bini Jolliet, Illinois fun Marie ati John Patrick (Agbẹ). Awọn óbi óṣèrè lóbinrin naa jẹ ijọ catholic ati Iran Irish-American. Óṣèrè lobinrin naa bẹrẹ irin ajo iṣẹ rẹ gẹgẹ̀bi óṣèrè ti radio ati ṣiṣè èrè ni Broadway ni ọdun 1930s[3].

McCambridge fẹ ọkọ rẹ akọkọ William Fifield ni ọdun 1939 ti wọn si bi ọmọ ọkunrin John Lawrence Fifield ni óṣu December, ọdun 1941. Tọkọ taya naa pinya ni ọdun 1946 leyin igbeyawó ọdun mèjè. Ni ọdun 1950, Óṣèrè lobinrin naa fẹ óṣèrè/producer/oludari Fletcher Markle. Tọkọ taya naa pinya ni ọdun 1962 lẹyin Igbeyawó ọdun mèjila. McCambridge ku ni óṣu March ni ọdun 2004 ni La Jolla, San Diego, California[4][5].

Ẹkọ

Mercedes jade lati collegi ti Mundelein ni ilù Chicago[6][7].

Ipà Óṣèrè lóbinrin ninu èrè àgbèlèwò

Ọdun Akọle Ipa Óṣèrè lóbinrin ninu èré àgbèlèwò Notes
1949 All the King's Men Sadie Burke Golden Globe Award for Best Supporting Actress
1951 Inside Straight Ada Stritch
1951 The Scarf Connie Carter
1951 Lightning Strikes Twice Liza McStringer
1951 Screen Snapshots: Hollywood Awards Herself short subject
1954 Johnny Guitar Emma Small
1956 Giant Luz Benedict Nominated – Academy Award for Best Supporting Actress
1957 A Farewell to Arms Miss Van Campen
1957 Wagon Train Emily Rossiter Episode: "The Emily Rossiter Story"
1958 Touch of Evil Gang leader Uncredited
1959 Suddenly, Last Summer Mrs. Grace Holly
1960 Rawhide Mrs Martha Mushgrove Episode: "Incident of the Captive"
1960 Rawhide Mrs Miller Episode: "Incident of the Curious Street"
1959 Riverboat Jessie Quinn Episode: "Jessie Quinn"
1960 Cimarron Mrs. Sarah Wyatt
1961 Angel Baby Sarah Strand
1962 Rawhide Ada Randolph Episode: "The Greedy Town"
1962 Bonanza Deborah Banning Episode: "The Lady from Baltimore"
1963 The Dakotas Jay French Episode: "Trouble at French Creek"
1965 Run Home Slow Nell Hagen
1965 Rawhide Ma Gufler Episode: "Hostage for Hanging"
1966 Lost in Space Sybilla Episode: "The Space Croppers"
1968 The Counterfeit Killer Frances
1968 Bewitched Carlotta Episode: "Darrin Gone! and Forgotten?"
1969 99 Women Thelma Diaz
1969 Justine Madame Dusbois
1970 Bonanza Matilda Curtis Episode: "The Law and Billy Burgess"
1971 Gunsmoke Rubilee Mather Episode: "The Lost"
1971 The Last Generation (archive footage)
1973 The President's Plane Is Missing Hester Madigan TV movie
1973 Sixteen Ma Irtley
1973 The Exorcist Pazuzu Voice
1975 Who Is the Black Dahlia? Grandmother TV movie
1977 Thieves Street Lady
1978 Charlie's Angels Norma Episode: "Angels in Springtime"
1978 Flying High Claire Episode: "In the Still of the Night"
1979 The Concorde ... Airport '79 Nelli
1979 The Sacketts Ma Sackett TV movie
1981 Magnum, P.I. Agatha Kimball Episode: "Don't Say Goodbye"
1983 Echoes Lillian Gerben
1986 Amazing Stories Miss Lestrange Voice, Episode: "Family Dog"
1988 Cagney & Lacey Sister Elizabeth Episode: "Land of the Free"
2018 The Other Side of the Wind Maggie Previously unreleased (final film role)

Ami Ẹyẹ ati Idànilọla

Latari ipa óṣèrè lóbinrin naa ni television ati aworan Motion ti Industry ni a fun ni irawọ mèji lori Hollywood Walk of Fame[8][9].

Awon Itokasi