Type a search term to find related articles by LIMS subject matter experts gathered from the most trusted and dynamic collaboration tools in the laboratory informatics industry.
Lila Kedrova | |
---|---|
Kedrova in 1965 | |
Ọjọ́ìbí | St. Petersburg, Russian Empire | 9 Oṣù Kẹ̀wá 1909
Aláìsí | 16 February 2000 Sault Ste. Marie, Ontario, Canada | (ọmọ ọdún 90)
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1938–1994 |
Olólùfẹ́ |
|
Elizaveta (Lila) Nikolaevna Kedrova (Russian: Елизавета (Лиля) Николаевна Кедрова; Oṣù kẹwàá ọjọ́ kẹsan, ọdún 1909[1][2] sí Oṣù Kejì, ọjọ́ kẹrin-dín-lógún, ọdún 2000) jẹ́ òṣèré obìnrin faransé tí wọ́n bí láti ìran Russia. Ó gba ẹ̀bùn ẹ̀yẹ fún òṣèré àtìlẹ́yìn obìnrin tó dára jùlọ fún Zorba the Greek (ọdún 1964), àti àmì ẹ̀yẹ Tony fún Best Performance láti ọwọ́ òṣèré obìnrin tó farahàn nínú eré orin kan fún iṣẹ́ eré kan náà fún fíìmù náà. [3]
<ref>
tag; no text was provided for refs named bio